Multi-talented Nigerian indigenous rapper and a KOD-signed music artist, Brymo has launched a new song called Okunrin Meta (Edun Okan).
Trending talented rapper and songwriter, Brymo unleashed this banging tune christened ”Okunrin Meta (Edun Okan)” released in the year 2022, to excites his music fans out there.
Brymo is a talented artist, who is a unique style of rap music, keeps amazing his music fans. The artist keeps moving his way forward any never dream of coming down.
Download Okunrin Meta (Edun Okan) mp3 by BrymoIn this song ”Okunrin Meta (Edun Okan)” Brymo is seen boosting his impression, which is potential rap music to listen to.
However, Now lets download and enjoy ”Okunrin Meta (Edun Okan)” by Brymo, as this sound will surely worth a place on your playlist.
Lyrics Brymo – Ọkùnrin Mẹ́ta (Ẹ̀dùn Ọkàn) Lyrics
Kó mi sí'ta
Fàmí lẹ'wù ya
Tẹ̀mí lọ́rùn pa
Ènìyàn lásán ni mo jẹ́
Mo fú'yẹ́ bíi paper
Ìjí jà lódò
Ó gbémi lọ sóko
Òhun l'ọkọ̀
Gbé mi lọ síbi tó kàn
Ògá tà ògá ò tà
Ọlọ'ọ'pá gba rìbá kàsà
Ẹ̀dùn ọkàn
Òhun l'ọkọ̀
Gbé mi lọ ibi mò ń lọ
Ẹ̀dùn ọkàn
Fún mi lọ́kàn
Ọkùnrin mẹ́ta dé'bi tí mò ń lọ
O ló'kùnkùn wọ gbó lọ
Mo fà á lẹ́'wù ya
Mo tẹ̀ l'ọ́rùn pa
Ènìyàn lásán mi ò jẹ́
Mo wíwo bí ẹ̀san
Èmi ni ìjì tó jà l'ódò
Tó gb'ọba wọn lọ s'óko
Òhun l'ọkọ̀
Gbé mi lọ síbi tó kàn
Ògá tà ògá ò tà
Ọlọ'ọ'pá gba rìbá kàsà
Ẹ̀dùn ọkàn
Òhun l'ọkọ̀
Gbé mi lọ ibi mò ń lọ
Ẹ̀dùn ọkàn
Fún mi lọ́kàn
Ọkùnrin mẹ́ta dé'bi tí mò ń lọ
Òhun l'ọkọ̀
Gbé mi lọ síbi tó kàn
Ògá tà ògá ò tà
Ọkùnrin mẹ́ta dé'bi tí mò n lọ